Top Stories
[FÍDÍÒ] Ọ̀rọ̀ kàbìtì: Ọwọ́ tẹ afurasí agbénipa méje tí wọ́n ń ta ẹ̀yà ara ènìyàn
![](https://www.trendynewsreporters.com/wp-content/uploads/2022/03/WhatsApp-Image-2022-03-25-at-5.26.43-PM.jpeg)
Victim of kidnapping in Ogun
Awon afurasí agbénipa méje ni owo agbofinro to ti te ni ipinle Ogun. Esun wipe won pa eniyan lati ta eya ara awon ni won fi kan won.